Non-discrimination Policy – Yoruba (èdè Yorùbá)

 

AKIYESI: Ti o ba nso ede Yoruba ofe ni iranlowo lori ede wa fun yin o. E pe ero ibanisoro yi [Number for Language Assistance Service] (TTY: [Number for TTY Service]).

 

Discrimination is Against the Law

Crater Community Hospice ba ilana ijoba apapo lori ofin eto ara ilu atipe a ko gbodo se ojusaju nipa eya, awo, ilu abinibi,ojo ori, abarapa tabi okunrin ati obinrin. Crater Community Hospice won ko gbodo yo awon eniyan si ile tabi wuwasi won yato latari eya, awon abinibi, ojo-ori, tabi okunrin abi obinrin.

Crater Community Hospice
  • Ipese ohun elo ofe ati iranlowo fun awon ti won le so ede lati le ma ba wa soro
    • Akosemose ogbufo odi
    • Kiko oro jade ni ona miran (kiko oro ni titobi, agbohunsile, awon ohun elo igbalode fun ero ayelujara ati awon ona miran.)
  • A npese ogbufo lofe fun awon ti won le so ede oyinbo daada,bii
    • Akosemose ogbufo
    • Kiko oro ni awon ede miran

Ti o ba nfe awon afani wonyi, e kansi [Compliance Officer]

Ti e ba nigbagbo that Crater Community Hospice ti kuna lati seto awon iranlowo wonyi tabi se ojusaju ni awon ona awon ona miran bi eleyameya, omo, ilu-abinibi, ojo-ori, abarapa, tabi okunrin abi obinrin, le fi iwe kotemi-lorun/iwe ifehonu han si: [Compliance Officer], 3916 South Crater Road, Petersburg, Virginia 23805, [Compliance Phone Number], TTY: [Number for TTY Service], [Compliance Fax Number], [Compliance Officer's Email]. E le fi iwe ifi ehonu han ni ojukoroju tabi nipa fifi ranse ni apo iwe si adiresi wa, fax, tabi ero-ayelujara. Ti eba nilo iranlowo lati ko iwe ifi-ehonu han, [Compliance Officer] wa ni sepe fun yin.

E tun le pe kotemilorun latari eto ara-ilu pelu eka eto ilera ati eto Fun ti ile Amerika. U.S Department of Health and Human Services, Office for Civil Rights, Office for Civil Rights Complain Portal, wa ni https://ocrportal.hhs.gov/ocr/portal/lobby.jsf tabi nipa fifi iwe sowo tabi lori ero- ibanisoro ni:

U.S Department of Health and Human Services

200 Independence Avenue, SW

Room 509F, HHH Buiding

Washington, D.C 20201

1800 – 868 -1019 – 800 – 537 – 7697 (TDD)

E le ri foomu fun ehonu ni http:/www.hhs.gov/ocr/office/file/index/html.